-
Mátíù 13:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ní, a máa fi kún ohun tó ní, a sì máa mú kó ní púpọ̀; àmọ́ ẹnikẹ́ni tí kò bá ní, a máa gba ohun tó ní pàápàá kúrò lọ́wọ́ rẹ̀.+
-
-
Mátíù 25:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Torí gbogbo ẹni tó bá ní, a máa fi kún èyí tó ní, ó sì máa ní ọ̀pọ̀ yanturu. Àmọ́ ẹni tí kò bá ní, a máa gba èyí tó ní pàápàá kúrò lọ́wọ́ rẹ̀.+
-