Lúùkù 19:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Wọ́n máa fọ́ ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ tó wà nínú rẹ mọ́lẹ̀,+ wọn ò sì ní fi òkúta kan sílẹ̀ lórí òkúta kan nínú rẹ,+ torí pé o ò fi òye mọ àkókò tí a máa bẹ̀ ọ́ wò.”
44 Wọ́n máa fọ́ ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ tó wà nínú rẹ mọ́lẹ̀,+ wọn ò sì ní fi òkúta kan sílẹ̀ lórí òkúta kan nínú rẹ,+ torí pé o ò fi òye mọ àkókò tí a máa bẹ̀ ọ́ wò.”