Mátíù 24:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tó jókòó sórí Òkè Ólífì, àwọn ọmọ ẹ̀yìn wá bá a ní òun nìkan, wọ́n sọ pé: “Sọ fún wa, ìgbà wo ni àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀, kí ló sì máa jẹ́ àmì pé o ti wà níhìn-ín*+ àti ti ìparí ètò àwọn nǹkan?”*+ Máàkù 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Sọ fún wa, ìgbà wo ni àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀, kí ló sì máa jẹ́ àmì ìgbà tí gbogbo nǹkan yìí máa wá sí òpin?”+
3 Nígbà tó jókòó sórí Òkè Ólífì, àwọn ọmọ ẹ̀yìn wá bá a ní òun nìkan, wọ́n sọ pé: “Sọ fún wa, ìgbà wo ni àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀, kí ló sì máa jẹ́ àmì pé o ti wà níhìn-ín*+ àti ti ìparí ètò àwọn nǹkan?”*+
4 “Sọ fún wa, ìgbà wo ni àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀, kí ló sì máa jẹ́ àmì ìgbà tí gbogbo nǹkan yìí máa wá sí òpin?”+