Mátíù 24:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ọ̀run àti ayé máa kọjá lọ, àmọ́ ó dájú pé àwọn ọ̀rọ̀ mi ò ní kọjá lọ.+ Máàkù 13:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ọ̀run àti ayé máa kọjá lọ,+ àmọ́ ó dájú pé àwọn ọ̀rọ̀ mi ò ní kọjá lọ.+