Jòhánù 12:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní báyìí, ìdààmú bá mi,*+ kí sì ni kí n sọ? Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí.+ Síbẹ̀, torí èyí ni mo fi wá sí wákàtí yìí. Hébérù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí Kristi wà ní ayé,* ó rawọ́ ẹ̀bẹ̀, ó sì fi ẹkún tó rinlẹ̀ àti omijé tọrọ+ lọ́wọ́ Ẹni tó lè gbà á lọ́wọ́ ikú, a sì gbọ́ ọ, a ṣojúure sí i torí pé ó ní ìbẹ̀rù Ọlọ́run.
27 Ní báyìí, ìdààmú bá mi,*+ kí sì ni kí n sọ? Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí.+ Síbẹ̀, torí èyí ni mo fi wá sí wákàtí yìí.
7 Nígbà tí Kristi wà ní ayé,* ó rawọ́ ẹ̀bẹ̀, ó sì fi ẹkún tó rinlẹ̀ àti omijé tọrọ+ lọ́wọ́ Ẹni tó lè gbà á lọ́wọ́ ikú, a sì gbọ́ ọ, a ṣojúure sí i torí pé ó ní ìbẹ̀rù Ọlọ́run.