Mátíù 27:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jésù wá dúró níwájú gómìnà, gómìnà sì bi í pé: “Ṣé ìwọ ni Ọba Àwọn Júù?” Jésù fèsì pé: “Ìwọ fúnra rẹ ti sọ ọ́.”+
11 Jésù wá dúró níwájú gómìnà, gómìnà sì bi í pé: “Ṣé ìwọ ni Ọba Àwọn Júù?” Jésù fèsì pé: “Ìwọ fúnra rẹ ti sọ ọ́.”+