Lúùkù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ní ọdún kẹẹ̀ẹ́dógún àkóso Tìbéríù Késárì, nígbà tí Pọ́ńtíù Pílátù jẹ́ gómìnà Jùdíà, tí Hẹ́rọ́dù*+ sì jẹ́ alákòóso agbègbè* Gálílì, tí Fílípì arákùnrin rẹ̀ jẹ́ alákòóso agbègbè ilẹ̀ Ítúréà àti Tírákónítì, tí Lísáníà sì jẹ́ alákòóso agbègbè Ábílénè,
3 Ní ọdún kẹẹ̀ẹ́dógún àkóso Tìbéríù Késárì, nígbà tí Pọ́ńtíù Pílátù jẹ́ gómìnà Jùdíà, tí Hẹ́rọ́dù*+ sì jẹ́ alákòóso agbègbè* Gálílì, tí Fílípì arákùnrin rẹ̀ jẹ́ alákòóso agbègbè ilẹ̀ Ítúréà àti Tírákónítì, tí Lísáníà sì jẹ́ alákòóso agbègbè Ábílénè,