Jòhánù 12:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn nǹkan yìí ò kọ́kọ́ yé àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, àmọ́ nígbà tí a ṣe Jésù lógo,+ wọ́n rántí pé a ti kọ àwọn nǹkan yìí nípa rẹ̀ àti pé wọ́n ṣe àwọn nǹkan yìí sí i.+
16 Àwọn nǹkan yìí ò kọ́kọ́ yé àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, àmọ́ nígbà tí a ṣe Jésù lógo,+ wọ́n rántí pé a ti kọ àwọn nǹkan yìí nípa rẹ̀ àti pé wọ́n ṣe àwọn nǹkan yìí sí i.+