-
Jòhánù 16:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀yin, ẹ̀dùn ọkàn bá yín báyìí; àmọ́ màá tún rí yín, inú yín sì máa dùn,+ ẹnì kankan ò sì ní gba ayọ̀ yín mọ́ yín lọ́wọ́.
-