Kólósè 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Òun ni àwòrán Ọlọ́run tí a kò lè rí,+ àkọ́bí nínú gbogbo ẹ̀dá; + Ìfihàn 19:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Mo rí i tí ọ̀run ṣí sílẹ̀, wò ó! ẹṣin funfun kan.+ A pe ẹni tó jókòó sórí rẹ̀ ní Ẹni Tó Ṣeé Gbára Lé+ àti Olóòótọ́,+ ó ń ṣèdájọ́, ó sì ń fi òdodo+ jagun lọ. Ìfihàn 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 ó wọ aṣọ àwọ̀lékè tí ẹ̀jẹ̀ wà lára rẹ̀,* orúkọ tí a sì ń pè é ni Ọ̀rọ̀+ Ọlọ́run.
11 Mo rí i tí ọ̀run ṣí sílẹ̀, wò ó! ẹṣin funfun kan.+ A pe ẹni tó jókòó sórí rẹ̀ ní Ẹni Tó Ṣeé Gbára Lé+ àti Olóòótọ́,+ ó ń ṣèdájọ́, ó sì ń fi òdodo+ jagun lọ.