ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Róòmù 8:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nítorí gbogbo àwọn tí ẹ̀mí Ọlọ́run ń darí ni ọmọ Ọlọ́run lóòótọ́.+

  • Róòmù 8:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ẹ̀mí fúnra rẹ̀ ń jẹ́rìí pẹ̀lú ẹ̀mí wa + pé ọmọ Ọlọ́run ni wá.+

  • 2 Kọ́ríńtì 6:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “‘Màá di bàbá yín,+ ẹ ó sì di ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mi,’+ ni Jèhófà,* Olódùmarè wí.”

  • Éfésù 1:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nítorí ó ti yàn wá ṣáájú+ kí ó lè sọ wá dọmọ+ nípasẹ̀ Jésù Kristi, torí ohun tí ó wù ú tí ó sì fẹ́ nìyẹn,+

  • 1 Jòhánù 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ẹ wo irú ìfẹ́ tí Baba ní sí wa+ tí a fi ń pè wá ní ọmọ Ọlọ́run!+ Ohun tí a sì jẹ́ nìyẹn. Ìdí nìyẹn tí ayé ò fi mọ̀ wá,+ torí kò tíì mọ̀ ọ́n.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́