Lúùkù 22:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Torí ta ló tóbi jù, ṣé ẹni tó ń jẹun* ni àbí ẹni tó ń gbé oúnjẹ wá?* Ṣebí ẹni tó ń jẹun* ni? Àmọ́ mo wà láàárín yín bí ẹni tó ń gbé oúnjẹ wá.*+
27 Torí ta ló tóbi jù, ṣé ẹni tó ń jẹun* ni àbí ẹni tó ń gbé oúnjẹ wá?* Ṣebí ẹni tó ń jẹun* ni? Àmọ́ mo wà láàárín yín bí ẹni tó ń gbé oúnjẹ wá.*+