Jòhánù 14:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Mo fi àlàáfíà sílẹ̀ fún yín; mo fún yín ní àlàáfíà mi.+ Mi ò fún yín lọ́nà tí ayé gbà ń fúnni. Ẹ má ṣe jẹ́ kí ìdààmú bá ọkàn yín, kí ìbẹ̀rù má sì mú kí ọkàn yín dà rú.
27 Mo fi àlàáfíà sílẹ̀ fún yín; mo fún yín ní àlàáfíà mi.+ Mi ò fún yín lọ́nà tí ayé gbà ń fúnni. Ẹ má ṣe jẹ́ kí ìdààmú bá ọkàn yín, kí ìbẹ̀rù má sì mú kí ọkàn yín dà rú.