Jòhánù 5:37, 38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Baba tó sì rán mi ti fúnra rẹ̀ jẹ́rìí nípa mi.+ Ẹ ò tíì gbọ́ ohùn rẹ̀ rí, ẹ ò sì fojú rí bó ṣe rí,+ 38 ẹ ò sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ rẹ̀ gbé inú yín, torí pé ẹ ò gba ẹni tó rán gbọ́.
37 Baba tó sì rán mi ti fúnra rẹ̀ jẹ́rìí nípa mi.+ Ẹ ò tíì gbọ́ ohùn rẹ̀ rí, ẹ ò sì fojú rí bó ṣe rí,+ 38 ẹ ò sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ rẹ̀ gbé inú yín, torí pé ẹ ò gba ẹni tó rán gbọ́.