Lúùkù 22:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Bó ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, wò ó! àwọn èrò dé, ọkùnrin tí wọ́n ń pè ní Júdásì, tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Méjìlá náà, ló ṣáájú wọn, ó sì sún mọ́ Jésù kó lè fẹnu kò ó lẹ́nu.+
47 Bó ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, wò ó! àwọn èrò dé, ọkùnrin tí wọ́n ń pè ní Júdásì, tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Méjìlá náà, ló ṣáájú wọn, ó sì sún mọ́ Jésù kó lè fẹnu kò ó lẹ́nu.+