Lúùkù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 èmi náà pinnu, torí mo ti wádìí ohun gbogbo láti ìbẹ̀rẹ̀ lọ́nà tó péye, pé kí n kọ ọ́ ránṣẹ́ sí ọ lẹ́sẹẹsẹ, ìwọ Tìófílọ́sì+ ọlọ́lá jù lọ, Lúùkù 3:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì,
3 èmi náà pinnu, torí mo ti wádìí ohun gbogbo láti ìbẹ̀rẹ̀ lọ́nà tó péye, pé kí n kọ ọ́ ránṣẹ́ sí ọ lẹ́sẹẹsẹ, ìwọ Tìófílọ́sì+ ọlọ́lá jù lọ,
23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì,