-
Ìṣe 4:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Pẹ̀lú agbára ńlá, àwọn àpọ́sítélì ń jẹ́rìí nìṣó nípa àjíǹde Jésù Olúwa,+ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí sì wà lórí gbogbo wọn lọ́pọ̀lọpọ̀.
-