ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 5:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ẹ máa yọ̀, kí inú yín sì dùn gidigidi,+ torí èrè yín+ pọ̀ ní ọ̀run, torí bí wọ́n ṣe ṣe inúnibíni sí àwọn wòlíì tó wà ṣáájú yín nìyẹn.+

  • Ìṣe 16:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Àmọ́ láàárín òru, Pọ́ọ̀lù àti Sílà ń gbàdúrà, wọ́n ń fi orin yin Ọlọ́run,+ àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì ń fetí sí wọn.

  • Róòmù 5:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ ẹ jẹ́ ká máa yọ̀* nígbà tí a bá wà nínú ìpọ́njú,+ torí a mọ̀ pé ìpọ́njú ń mú ìfaradà wá;+

  • 2 Kọ́ríńtì 12:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí náà, mò ń láyọ̀ nínú àìlera, nínú ìwọ̀sí, ní àkókò àìní, nínú inúnibíni àti ìṣòro, nítorí Kristi. Torí nígbà tí mo bá jẹ́ aláìlera, ìgbà náà ni mo di alágbára.+

  • Fílípì 1:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 A ti fún yín ní àǹfààní náà nítorí Kristi, kì í ṣe láti ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀ nìkan, àmọ́ láti jìyà nítorí rẹ̀ pẹ̀lú.+

  • Hébérù 10:34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Torí ẹ bá àwọn tó wà ní ẹ̀wọ̀n kẹ́dùn, ẹ sì fi ayọ̀ gba bí wọ́n ṣe kó ẹrù yín,+ torí ẹ mọ̀ pé ẹ̀yin fúnra yín ní ohun ìní tó dáa jù, tó sì wà pẹ́ títí.+

  • 1 Pétérù 4:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa yọ̀+ torí ibi tí ẹ lè bá Kristi jìyà dé,+ kí ẹ̀yin pẹ̀lú lè yọ̀, kí ayọ̀ yín sì kún nígbà ìfihàn ògo rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́