Diutarónómì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ yan àwọn ọkùnrin tó jẹ́ ọlọ́gbọ́n àti olóye, tí wọ́n sì ní ìrírí látinú àwọn ẹ̀yà yín, màá sì fi wọ́n ṣe olórí yín.’+
13 Ẹ yan àwọn ọkùnrin tó jẹ́ ọlọ́gbọ́n àti olóye, tí wọ́n sì ní ìrírí látinú àwọn ẹ̀yà yín, màá sì fi wọ́n ṣe olórí yín.’+