ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 28:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Wò ó! Jésù pàdé wọn, ó sì sọ pé: “Ẹ ǹlẹ́ o!” Wọ́n sún mọ́ ọn, wọ́n di ẹsẹ̀ rẹ̀ mú, wọ́n sì tẹrí ba* fún un.

  • Jòhánù 20:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Nígbà tí ọjọ́ ti lọ lọ́jọ́ yẹn, ní ọjọ́ kìíní ọ̀sẹ̀, tí ilẹ̀kùn ibi tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn wà sì wà ní títì pa torí pé wọ́n ń bẹ̀rù àwọn Júù, Jésù wá, ó dúró ní àárín wọn, ó sì sọ fún wọn pé: “Àlàáfíà fún yín o.”+

  • 1 Kọ́ríńtì 15:4-7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 àti pé a sin ín,+ bẹ́ẹ̀ ni, pé a jí i dìde+ ní ọjọ́ kẹta+ bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+ 5 àti pé ó fara han Kéfà,*+ lẹ́yìn náà, àwọn Méjìlá náà.+ 6 Lẹ́yìn ìyẹn, ó fara han èyí tó ju ọgọ́rùn-ún márùn-ún (500) àwọn ará lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo,+ púpọ̀ nínú wọn ṣì wà pẹ̀lú wa, bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn díẹ̀ ti sùn nínú ikú. 7 Lẹ́yìn ìyẹn, ó fara han Jémíìsì,+ lẹ́yìn náà, gbogbo àpọ́sítélì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́