Ìṣe 25:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó sọ pé: “Torí náà, kí àwọn tó wà nípò àṣẹ láàárín yín bá mi lọ, kí wọ́n sì fẹ̀sùn kàn án, tó bá jẹ́ pé òótọ́ ni ọkùnrin náà ti ṣe ohun tí kò tọ́.”+
5 Ó sọ pé: “Torí náà, kí àwọn tó wà nípò àṣẹ láàárín yín bá mi lọ, kí wọ́n sì fẹ̀sùn kàn án, tó bá jẹ́ pé òótọ́ ni ọkùnrin náà ti ṣe ohun tí kò tọ́.”+