Ìṣe 9:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àmọ́ Sọ́ọ̀lù ń gba agbára kún agbára, ó sì ń pa àwọn Júù tó ń gbé ní Damásíkù lẹ́nu mọ́, bí ó ṣe ń fi ẹ̀rí tó bọ́gbọ́n mu hàn pé Jésù ni Kristi náà.+
22 Àmọ́ Sọ́ọ̀lù ń gba agbára kún agbára, ó sì ń pa àwọn Júù tó ń gbé ní Damásíkù lẹ́nu mọ́, bí ó ṣe ń fi ẹ̀rí tó bọ́gbọ́n mu hàn pé Jésù ni Kristi náà.+