11 Olúwa sọ fún un pé: “Dìde, lọ sí ojú ọ̀nà tí wọ́n ń pè ní Títọ́, kí o sì wá ọkùnrin kan tó ń jẹ́ Sọ́ọ̀lù láti Tásù+ ní ilé Júdásì. Wò ó! ó ń gbàdúrà,
15 Àmọ́ Olúwa sọ fún un pé: “Lọ! nítorí ohun èlò tí a ti yàn ni ọkùnrin yìí jẹ́ fún mi+ láti mú orúkọ mi lọ sọ́dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè+ àti àwọn ọba+ àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.