-
Ìṣe 3:25, 26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ẹ̀yin ni ọmọ àwọn wòlíì àti ti májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá àwọn baba ńlá yín dá,+ tí ó sọ fún Ábúráhámù pé: ‘Gbogbo ìdílé tó wà láyé yóò rí ìbùkún nípasẹ̀ ọmọ* rẹ.’+ 26 Ẹ̀yin ni Ọlọ́run kọ́kọ́ rán Ìránṣẹ́ rẹ̀ sí,+ lẹ́yìn tí ó gbé e dìde, kí ó lè bù kún yín láti mú kí ẹnì kọ̀ọ̀kan yín yí pa dà kúrò nínú àwọn iṣẹ́ ibi rẹ̀.”
-