Kólósè 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 A sin yín pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìbatisí rẹ̀,+ àjọṣe tí ẹ sì ní pẹ̀lú rẹ̀ mú kí a gbé ẹ̀yin náà dìde+ pẹ̀lú rẹ̀ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ yín nínú iṣẹ́ agbára Ọlọ́run, ẹni tó gbé e dìde kúrò nínú ikú.+
12 A sin yín pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìbatisí rẹ̀,+ àjọṣe tí ẹ sì ní pẹ̀lú rẹ̀ mú kí a gbé ẹ̀yin náà dìde+ pẹ̀lú rẹ̀ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ yín nínú iṣẹ́ agbára Ọlọ́run, ẹni tó gbé e dìde kúrò nínú ikú.+