Sáàmù 103:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Jèhófà ti fìdí ìtẹ́ rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in ní ọ̀run;+Ìjọba rẹ̀ sì ń ṣàkóso lórí ohun gbogbo.+ Jeremáyà 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣùgbọ́n Jèhófà ni Ọlọ́run lóòótọ́. Òun ni Ọlọ́run alààyè+ àti Ọba ayérayé.+ Nítorí ìbínú rẹ̀, ayé á mì jìgìjìgì,+Kò sì sí orílẹ̀-èdè tó lè fara da ìdálẹ́bi rẹ̀. Ìfihàn 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+
10 Ṣùgbọ́n Jèhófà ni Ọlọ́run lóòótọ́. Òun ni Ọlọ́run alààyè+ àti Ọba ayérayé.+ Nítorí ìbínú rẹ̀, ayé á mì jìgìjìgì,+Kò sì sí orílẹ̀-èdè tó lè fara da ìdálẹ́bi rẹ̀.
3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+