1 Tímótì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí ìjẹ́rìí yìí + ni a ṣe yàn mí láti jẹ́ oníwàásù àti àpọ́sítélì+—òótọ́ ni mò ń sọ, mi ò parọ́—olùkọ́ àwọn orílẹ̀-èdè+ ní ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́ àti òtítọ́.
7 Torí ìjẹ́rìí yìí + ni a ṣe yàn mí láti jẹ́ oníwàásù àti àpọ́sítélì+—òótọ́ ni mò ń sọ, mi ò parọ́—olùkọ́ àwọn orílẹ̀-èdè+ ní ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́ àti òtítọ́.