Róòmù 9:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 tó sì ṣe èyí láti jẹ́ ká mọ ọrọ̀ ògo rẹ̀ lórí àwọn ohun èlò àánú,+ èyí tó ti pèsè sílẹ̀ fún ògo, 24 ìyẹn àwa tí ó pè, kì í ṣe láti àárín àwọn Júù nìkan, àmọ́ láti àárín àwọn orílẹ̀-èdè+ pẹ̀lú, kí wá ni ká sọ?
23 tó sì ṣe èyí láti jẹ́ ká mọ ọrọ̀ ògo rẹ̀ lórí àwọn ohun èlò àánú,+ èyí tó ti pèsè sílẹ̀ fún ògo, 24 ìyẹn àwa tí ó pè, kì í ṣe láti àárín àwọn Júù nìkan, àmọ́ láti àárín àwọn orílẹ̀-èdè+ pẹ̀lú, kí wá ni ká sọ?