14 Símíónì+ ti ròyìn ní kíkún bí Ọlọ́run ṣe yí àfiyèsí rẹ̀ sí àwọn orílẹ̀-èdè fún ìgbà àkọ́kọ́ kí ó lè mú àwọn èèyàn kan jáde fún orúkọ rẹ̀ látinú wọn.+
7 Dípò bẹ́ẹ̀, nígbà tí wọ́n rí i pé a ti fi sí ìkáwọ́ mi láti sọ ìhìn rere fún àwọn tó jẹ́ aláìdádọ̀dọ́,*+ gẹ́gẹ́ bí a ṣe fi sí ìkáwọ́ Pétérù láti sọ ọ́ fún àwọn tó dádọ̀dọ́,*