Gálátíà 6:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Yàtọ̀ síyẹn, kí ẹni tí à ń kọ́* ní ọ̀rọ̀ náà máa ṣàjọpín ohun rere gbogbo pẹ̀lú ẹni tó ń kọ́ni* ní irú ẹ̀kọ́ bẹ́ẹ̀.+ Hébérù 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Bákan náà, ẹ má gbàgbé láti máa ṣe rere, kí ẹ sì máa pín ohun tí ẹ ní pẹ̀lú àwọn ẹlòmíì,+ torí inú Ọlọ́run máa ń dùn gan-an sí irú àwọn ẹbọ bẹ́ẹ̀.+
6 Yàtọ̀ síyẹn, kí ẹni tí à ń kọ́* ní ọ̀rọ̀ náà máa ṣàjọpín ohun rere gbogbo pẹ̀lú ẹni tó ń kọ́ni* ní irú ẹ̀kọ́ bẹ́ẹ̀.+
16 Bákan náà, ẹ má gbàgbé láti máa ṣe rere, kí ẹ sì máa pín ohun tí ẹ ní pẹ̀lú àwọn ẹlòmíì,+ torí inú Ọlọ́run máa ń dùn gan-an sí irú àwọn ẹbọ bẹ́ẹ̀.+