1 Tẹsalóníkà 5:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí náà, ẹ máa fún ara yín níṣìírí,* kí ẹ sì máa gbé ara yín ró,+ bí ẹ ti ń ṣe ní tòótọ́. Hébérù 10:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 ká má ṣe máa kọ ìpàdé wa sílẹ̀,+ bí àṣà àwọn kan, àmọ́ ká máa gba ara wa níyànjú,+ ní pàtàkì jù lọ bí ẹ ṣe ń rí i pé ọjọ́ náà ń sún mọ́lé.+
25 ká má ṣe máa kọ ìpàdé wa sílẹ̀,+ bí àṣà àwọn kan, àmọ́ ká máa gba ara wa níyànjú,+ ní pàtàkì jù lọ bí ẹ ṣe ń rí i pé ọjọ́ náà ń sún mọ́lé.+