Ìṣe 19:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn tí àwọn nǹkan yìí ti ṣẹlẹ̀, Pọ́ọ̀lù pinnu lọ́kàn rẹ̀ pé, lẹ́yìn tí òun bá ti la Makedóníà+ àti Ákáyà kọjá, òun á rìnrìn àjò lọ sí Jerúsálẹ́mù.+ Ó sọ pé: “Lẹ́yìn tí mo bá lọ síbẹ̀, mo gbọ́dọ̀ dé Róòmù pẹ̀lú.”+
21 Lẹ́yìn tí àwọn nǹkan yìí ti ṣẹlẹ̀, Pọ́ọ̀lù pinnu lọ́kàn rẹ̀ pé, lẹ́yìn tí òun bá ti la Makedóníà+ àti Ákáyà kọjá, òun á rìnrìn àjò lọ sí Jerúsálẹ́mù.+ Ó sọ pé: “Lẹ́yìn tí mo bá lọ síbẹ̀, mo gbọ́dọ̀ dé Róòmù pẹ̀lú.”+