Ìṣe 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́ Jèhófà,* tí wọ́n sì ń gbààwẹ̀, ẹ̀mí mímọ́ sọ pé: “Ẹ ya Bánábà àti Sọ́ọ̀lù+ sọ́tọ̀ fún mi kí wọ́n lè ṣe iṣẹ́ tí mo pè wọ́n sí.”+
2 Bí wọ́n ṣe ń ṣiṣẹ́ Jèhófà,* tí wọ́n sì ń gbààwẹ̀, ẹ̀mí mímọ́ sọ pé: “Ẹ ya Bánábà àti Sọ́ọ̀lù+ sọ́tọ̀ fún mi kí wọ́n lè ṣe iṣẹ́ tí mo pè wọ́n sí.”+