Róòmù 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí a máa lépa àwọn ohun tó ń mú kí àlàáfíà wà+ àti àwọn ohun tó ń gbé ẹnì kejì wa ró.+ Róòmù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí kálukú wa máa ṣe ohun tó wu ọmọnìkejì rẹ̀ fún ire rẹ̀, láti gbé e ró.+
19 Nítorí náà, ẹ jẹ́ kí a máa lépa àwọn ohun tó ń mú kí àlàáfíà wà+ àti àwọn ohun tó ń gbé ẹnì kejì wa ró.+