Mátíù 12:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Wò ó! Ìránṣẹ́ mi+ tí mo yàn, àyànfẹ́ mi, ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Màá fi ẹ̀mí mi sára rẹ̀,+ ó sì máa jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo ṣe kedere sí àwọn orílẹ̀-èdè. Mátíù 12:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ní tòótọ́, àwọn orílẹ̀-èdè máa ní ìrètí nínú orúkọ rẹ̀.”+ Ìṣe 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Yàtọ̀ síyẹn, kò sí ìgbàlà lọ́dọ̀ ẹlòmíì, nítorí kò sí orúkọ míì+ lábẹ́ ọ̀run tí a fún àwọn èèyàn tí a lè tipasẹ̀ rẹ̀ rí ìgbàlà.”+
18 “Wò ó! Ìránṣẹ́ mi+ tí mo yàn, àyànfẹ́ mi, ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Màá fi ẹ̀mí mi sára rẹ̀,+ ó sì máa jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo ṣe kedere sí àwọn orílẹ̀-èdè.
12 Yàtọ̀ síyẹn, kò sí ìgbàlà lọ́dọ̀ ẹlòmíì, nítorí kò sí orúkọ míì+ lábẹ́ ọ̀run tí a fún àwọn èèyàn tí a lè tipasẹ̀ rẹ̀ rí ìgbàlà.”+