-
Ìṣe 26:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àmọ́ mo sọ pé: ‘Ta ni ọ́, Olúwa?’ Olúwa sì fèsì pé: ‘Èmi ni Jésù, ẹni tí ò ń ṣe inúnibíni sí. 16 Ní báyìí, dìde dúró lórí ẹsẹ̀ rẹ. Ìdí tí mo fi fara hàn ọ́ ni pé, mo fẹ́ yàn ọ́ ṣe ìránṣẹ́ àti ẹlẹ́rìí àwọn ohun tí o ti rí àti àwọn ohun tí màá mú kí o rí nípa mi.+
-