Ìṣe 16:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 láti ibẹ̀, a lọ sí ìlú Fílípì,+ ìlú tí wọ́n ń ṣàkóso rẹ̀ láti òkèèrè, tó jẹ́ olú ìlú ní agbègbè Makedóníà. A sì lo ọjọ́ díẹ̀ ní ìlú yìí.
12 láti ibẹ̀, a lọ sí ìlú Fílípì,+ ìlú tí wọ́n ń ṣàkóso rẹ̀ láti òkèèrè, tó jẹ́ olú ìlú ní agbègbè Makedóníà. A sì lo ọjọ́ díẹ̀ ní ìlú yìí.