1 Tímótì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọ̀rọ̀ yìí ṣeé gbára lé: Tí ọkùnrin kan bá ń sapá láti di alábòójútó,+ iṣẹ́ rere ló fẹ́ ṣe. 1 Tímótì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bákan náà, kí àwọn ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ jẹ́ ẹni tó ń fọwọ́ pàtàkì mú nǹkan, kí wọ́n má ṣe jẹ́ ẹlẹ́nu méjì,* kí wọ́n má ṣe máa mu ọtí* lámujù, kí wọ́n má ṣe máa wá èrè tí kò tọ́,+
8 Bákan náà, kí àwọn ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ jẹ́ ẹni tó ń fọwọ́ pàtàkì mú nǹkan, kí wọ́n má ṣe jẹ́ ẹlẹ́nu méjì,* kí wọ́n má ṣe máa mu ọtí* lámujù, kí wọ́n má ṣe máa wá èrè tí kò tọ́,+