Róòmù 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí náà, kí a má ṣe máa dá ara wa lẹ́jọ́ mọ́,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ pinnu pé ẹ ò ní fi ohun ìkọ̀sẹ̀ tàbí ohun ìdènà síwájú arákùnrin yín.+ Róòmù 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ohun tó dáa jù ni pé kéèyàn má jẹ ẹran tàbí kó má mu ọtí tàbí kó má ṣe ohunkóhun tó máa mú arákùnrin rẹ̀ kọsẹ̀.+
13 Torí náà, kí a má ṣe máa dá ara wa lẹ́jọ́ mọ́,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ pinnu pé ẹ ò ní fi ohun ìkọ̀sẹ̀ tàbí ohun ìdènà síwájú arákùnrin yín.+
21 Ohun tó dáa jù ni pé kéèyàn má jẹ ẹran tàbí kó má mu ọtí tàbí kó má ṣe ohunkóhun tó máa mú arákùnrin rẹ̀ kọsẹ̀.+