ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Éfésù 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nítorí èyí, èmi, Pọ́ọ̀lù, ẹlẹ́wọ̀n + Kristi Jésù nítorí yín, ẹ̀yin èèyàn orílẹ̀-èdè,

  • Fílípì 1:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 tó fi jẹ́ pé gbogbo èèyàn mọ̀+ nípa àwọn ìdè ẹ̀wọ̀n mi+ nítorí Kristi láàárín gbogbo Ẹ̀ṣọ́ Ọba àti gbogbo àwọn yòókù.

  • Kólósè 4:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ìkíni èmi Pọ́ọ̀lù nìyí, tí mo fi ọwọ́ ara mi kọ.+ Ẹ máa fi ìdè ẹ̀wọ̀n mi+ sọ́kàn. Kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí wà pẹ̀lú yín.

  • 2 Tímótì 1:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Torí náà, má ṣe tijú láti jẹ́rìí nípa Olúwa wa+ tàbí èmi, ẹlẹ́wọ̀n nítorí rẹ̀, àmọ́ kí ìwọ náà jìyà torí ìhìn rere,+ kí o sì gbára lé agbára Ọlọ́run.+

  • Fílémónì 13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nítorí ìwọ ò sí níbí, ó wù mí kó ṣì wà lọ́dọ̀ mi, kó lè máa ràn mí lọ́wọ́ lákòókò yìí tí mo wà lẹ́wọ̀n nítorí ìhìn rere.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́