2 Kọ́ríńtì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nítorí Ọmọ Ọlọ́run, Jésù Kristi, tí a wàásù rẹ̀ láàárín yín, ìyẹn nípasẹ̀ èmi àti Sílífánù* pẹ̀lú Tímótì,+ kò di “bẹ́ẹ̀ ni” kó tún wá jẹ́ “bẹ́ẹ̀ kọ́,” àmọ́ “bẹ́ẹ̀ ni” ti di “bẹ́ẹ̀ ni” nínú ọ̀rọ̀ tirẹ̀.
19 Nítorí Ọmọ Ọlọ́run, Jésù Kristi, tí a wàásù rẹ̀ láàárín yín, ìyẹn nípasẹ̀ èmi àti Sílífánù* pẹ̀lú Tímótì,+ kò di “bẹ́ẹ̀ ni” kó tún wá jẹ́ “bẹ́ẹ̀ kọ́,” àmọ́ “bẹ́ẹ̀ ni” ti di “bẹ́ẹ̀ ni” nínú ọ̀rọ̀ tirẹ̀.