Róòmù 8:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Yàtọ̀ síyẹn, àwọn tó yàn ṣáájú+ ni àwọn tó pè;+ àwọn tó pè ni àwọn tó kéde ní olódodo.+ Níkẹyìn, àwọn tó kéde ní olódodo ni àwọn tó ṣe lógo.+
30 Yàtọ̀ síyẹn, àwọn tó yàn ṣáájú+ ni àwọn tó pè;+ àwọn tó pè ni àwọn tó kéde ní olódodo.+ Níkẹyìn, àwọn tó kéde ní olódodo ni àwọn tó ṣe lógo.+