1 Tẹsalóníkà 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Lẹ́yìn náà, àwa alààyè tí a kù nílẹ̀ ni a ó gbà lọ pẹ̀lú wọn nínú àwọsánmà+ láti pàdé Olúwa+ nínú afẹ́fẹ́; a ó sì tipa báyìí máa wà pẹ̀lú Olúwa nígbà gbogbo.+
17 Lẹ́yìn náà, àwa alààyè tí a kù nílẹ̀ ni a ó gbà lọ pẹ̀lú wọn nínú àwọsánmà+ láti pàdé Olúwa+ nínú afẹ́fẹ́; a ó sì tipa báyìí máa wà pẹ̀lú Olúwa nígbà gbogbo.+