ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Tímótì 4:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Àmọ́, má ṣe tẹ́tí sí àwọn ìtàn èké+ tí kò buyì kúnni, irú èyí tí àwọn obìnrin tó ti darúgbó máa ń sọ. Kàkà bẹ́ẹ̀, kọ́ ara rẹ láti fi ìfọkànsin Ọlọ́run ṣe àfojúsùn rẹ.

  • 2 Tímótì 4:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Torí ìgbà kan ń bọ̀ tí wọn ò ní tẹ̀ lé ẹ̀kọ́ tó ṣàǹfààní,*+ àmọ́ wọ́n á máa ṣe ìfẹ́ inú ara wọn, wọ́n á fi àwọn olùkọ́ yí ara wọn ká, kí wọ́n lè máa sọ ohun tí wọ́n fẹ́ gbọ́.*+ 4 Wọn ò ní fetí sí òtítọ́ mọ́, ìtàn èké ni wọ́n á máa fetí sí.

  • Títù 1:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Òótọ́ ni ẹ̀rí yìí. Torí náà, máa bá wọn wí lọ́nà tó múná, kí ìgbàgbọ́ wọn lè lágbára, 14 kí wọ́n má ṣe fiyè sí ìtàn àròsọ àwọn Júù àti àṣẹ àwọn èèyàn tí wọ́n ti kúrò nínú òtítọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́