24 Lóòótọ́-lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ẹnikẹ́ni tó bá gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, tó sì gba Ẹni tó rán mi gbọ́, ní ìyè àìnípẹ̀kun,+ a ò sì ní dá a lẹ́jọ́, àmọ́ ó ti tinú ikú bọ́ sínú ìyè.+
2 (òótọ́ ni, a fi ìyè náà hàn kedere, a ti rí ìyè àìnípẹ̀kun+ tó wà pẹ̀lú Baba, tí a fi hàn kedere fún wa, à ń jẹ́rìí fún yín nípa rẹ̀,+ a sì ń ròyìn rẹ̀ fún yín),