-
Ìṣe 9:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Nítorí màá fi hàn án ní kedere bí ìyà tó máa jẹ nítorí orúkọ mi ṣe máa pọ̀ tó.”+
-
-
Éfésù 3:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nítorí èyí, èmi, Pọ́ọ̀lù, ẹlẹ́wọ̀n + Kristi Jésù nítorí yín, ẹ̀yin èèyàn orílẹ̀-èdè,
-