2 Kọ́ríńtì 4:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àmọ́ a ti kọ àwọn ohun ìtìjú tí kò ṣeé gbọ́ sétí sílẹ̀ pátápátá, a kò rin ìrìn ẹ̀tàn, bẹ́ẹ̀ ni a kò ṣe àbùlà ọ̀rọ̀ Ọlọ́run;+ àmọ́ bí a ṣe ń fi òtítọ́ hàn kedere, à ń dámọ̀ràn ara wa fún ẹ̀rí ọkàn gbogbo èèyàn níwájú Ọlọ́run.+
2 Àmọ́ a ti kọ àwọn ohun ìtìjú tí kò ṣeé gbọ́ sétí sílẹ̀ pátápátá, a kò rin ìrìn ẹ̀tàn, bẹ́ẹ̀ ni a kò ṣe àbùlà ọ̀rọ̀ Ọlọ́run;+ àmọ́ bí a ṣe ń fi òtítọ́ hàn kedere, à ń dámọ̀ràn ara wa fún ẹ̀rí ọkàn gbogbo èèyàn níwájú Ọlọ́run.+