1 Tímótì 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Tí o bá fún àwọn ará ní ìtọ́ni yìí, o máa jẹ́ òjíṣẹ́ rere fún Kristi Jésù, tí a fi àwọn ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́ bọ́ àti ẹ̀kọ́ rere, èyí tí o ti tẹ̀ lé pẹ́kípẹ́kí.+
6 Tí o bá fún àwọn ará ní ìtọ́ni yìí, o máa jẹ́ òjíṣẹ́ rere fún Kristi Jésù, tí a fi àwọn ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́ bọ́ àti ẹ̀kọ́ rere, èyí tí o ti tẹ̀ lé pẹ́kípẹ́kí.+