Róòmù 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní báyìí, tí ẹ̀mí ẹni tó gbé Jésù dìde kúrò nínú ikú bá ń gbé inú yín, ẹni tó gbé Kristi Jésù dìde kúrò nínú ikú+ pẹ̀lú yóò fi ẹ̀mí rẹ̀ tó ń gbé inú yín sọ ara kíkú yín di ààyè.+
11 Ní báyìí, tí ẹ̀mí ẹni tó gbé Jésù dìde kúrò nínú ikú bá ń gbé inú yín, ẹni tó gbé Kristi Jésù dìde kúrò nínú ikú+ pẹ̀lú yóò fi ẹ̀mí rẹ̀ tó ń gbé inú yín sọ ara kíkú yín di ààyè.+