-
Ìṣe 19:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Èyí ń bá a lọ fún ọdún méjì, tí gbogbo àwọn tó ń gbé ní ìpínlẹ̀ Éṣíà fi gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa, àti Júù àti Gíríìkì.